Ó
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IKINNI
Obara ni kosio
Adifafun Oloja komodin
Igba ti nfomi oju sogbere ire gbogbo
Ebo ni wonni kose
Osi gbebo nbe orubo
Ruru ebo
Eru atukesu
Kepe
Kejina
Ewa bawa ni jebutu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe ki lleyi o mon
bo oun dada ifa igba ti kofi
okan si ni oun osan lore re pada
ki elleyi otoju omo dada
ko mon so pe kosi iyonu
lori omo ko mon pada wadi
wahala si lorun
lojo iwaju
Ki eleyi orubo ogbo ki ole ba dagbalagba laye ki osi mon ba dagbalagba yeye
ki elleyi otete rubo ki aye oma ba gba gbogbo ogbon ti nbe ninu eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eyele meta
agbebo adie meta
eku ati eja
meta meta
epo ati eko
kofi ewe oniyemiye
kun ebo to bafe rubo naa
kofi eyele
ati akuko adie rubo naa
pelu epo ati eko
Alabahun meji
Igbin apinnu emeji
Akuko adie meji
Epo ati eko
Akuko adie meta
Eja ajabo odo meta
Ogede omini topo dada
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni eruko idi
Abidi sin
Adifafun aje osuna
Anamon naye ana agbalagba
Sa jinnijinni
Igbati nto run bo wa saye
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Keepe
Keejina
Aje wadi apesin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ki eleyi orubo
ki won le mon wa si aarin
ire ki osi lebadi eni iyi lawujo
ki aye mon ponle
ki elleyi orubo
ntori omo kik osi mon se
agbere ki o le ba di olomo laye
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
agbebo adie meji
eyele funfun meji
fun aje pelu oyin
epo ati eko
agbabo adie meji
pelu odidid okete fun
awon agbalagba
epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ao fi ogde yije iyere osun naa
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Iyere osun aote ni obara iwori
Ipepe ara omo owu alagbede ao lo pelu eyo atare mesan
Aote iyerosun ni obara obodi aose adure si dada pelu isegun ao da papo mon ipepe ti agun yen ao fi sin gbere si gbogbo oriklerikeri ara wa ao wa da iyoku sinu omi iwe ao fi sanra.
Ewe ojusaju topo dada ao lo afi se igbin apinu meji lepo niyo ao te ifa obara obodi iyereosuns ao wa sw adure si dada ao koje
MEDICINE
Explore Ifa
Óbárà Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Iwòrì Odu.
