O
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
Read This Odu in Other Languages
Verse-level switching (Yoruba, English, Spanish, Portuguese, French) is available directly inside each verse below.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Obara fun nigin nigin
Adifafun ope eluju
Ti ogarun gase ntori ire
Adifafun ope eluju
Ti ogarun gase ntori ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki orubo ntori ore
Ti nbo fun ki ore naa ba
Sonu mon lowo
Ti nbo fun ki ore naa ba
Sonu mon lowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Pelu eyele meji
Pelu epo ati eko
Pelu obi
Pelu eyele meji
Pelu epo ati eko
Pelu obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Olobara funfun ninini
Adifafun bara ti n lo
Oko ailero odun
Adifafun bara ti n lo
Oko ailero odun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi omon se
Ai gboro si nkan ti
Awon awo ba so fun won
Ki o mun oro nani okun kundun
Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni ola awon ala ti o da ifa si ni ibi kan nbe ninu ile re to bo ibe lawon ajogun ngba wole ko ole ati simeti kopo papo mo arawon ko fidi ibi ko fi ewe alupaida ati ewe agbesi kun ebo ru
Ai gboro si nkan ti
Awon awo ba so fun won
Ki o mun oro nani okun kundun
Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni ola awon ala ti o da ifa si ni ibi kan nbe ninu ile re to bo ibe lawon ajogun ngba wole ko ole ati simeti kopo papo mo arawon ko fidi ibi ko fi ewe alupaida ati ewe agbesi kun ebo ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo ati eko
Eyele
Akuko adie
Opolopo owo
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo ati eko
Eyele
Akuko adie
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara funfun ringinringin
Adifafun eku ti n lo le
Ji obinrin ebiti
Adifafun eku ti n lo le
Ji obinrin ebiti
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon
Ja eni kejire lole
To ba danwo iku ni ere re
ifa pere fun eni to da ifa ni ko rubo ki ire oba le ya ile re ki ire to be ko ma ba ja de ko fi akara elepo bo ifa
Ja eni kejire lole
To ba danwo iku ni ere re
ifa pere fun eni to da ifa ni ko rubo ki ire oba le ya ile re ki ire to be ko ma ba ja de ko fi akara elepo bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Eyin pepeye mejo
Eko eda meji
Epo ati eko
Akara elepo
Eyele
Akuko adire
Opolopo owo
Eyin pepeye mejo
Eko eda meji
Epo ati eko
Akara elepo
Eyele
Akuko adire
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Obara funfun ringring
Adifafun orunmila
Baba n lole fun ntori aje
Adifafun orunmila
Baba n lole fun ntori aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi
Olobo aje koleri
Aje jeun ki aje mon
Ba won eleyi
ifa pere fun eni toda ogunda bede ifa ni awon ota po fun korubo kole ba segun ko fi irere meji ni o je bayen
Olobo aje koleri
Aje jeun ki aje mon
Ba won eleyi
ifa pere fun eni toda ogunda bede ifa ni awon ota po fun korubo kole ba segun ko fi irere meji ni o je bayen
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele funfun fun aje
Agbebo adie meji
Fun ebo
Akuko adie fun
Isegun
Epo ati eko pelu obi.
Irere meji
Eyele
Opolopo owo
Akuko adie
Agbebo adie meji
Fun ebo
Akuko adie fun
Isegun
Epo ati eko pelu obi.
Irere meji
Eyele
Opolopo owo
Akuko adie
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ogomon ope ewe emile
Iyere ao lopapo
Afise igbin meji lepo niyo je
Ao te iyere osun ni obara ofun
Ao se adura si dada
Ao je gbogbo re pata
Gbongbo oju ona to ta koja aogo ao yo larin ao lopo mo iyere ao fi se igbin meji lodidi lepo niyio
Iyere ao lopapo
Afise igbin meji lepo niyo je
Ao te iyere osun ni obara ofun
Ao se adura si dada
Ao je gbogbo re pata
Gbongbo oju ona to ta koja aogo ao yo larin ao lopo mo iyere ao fi se igbin meji lodidi lepo niyio
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao bu die lara esu tin gbebo ao lo tiyo kunna dada ao ma fi epo pupa la ni ale tia ba ti fe sun
Explore Ifa
Obara Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Oyeku, Obara Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Ofun Odu.
