Ó
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Kise ifa afi lande
Adifafun orunmila baba nsukun
Alailenikankan
Ebo ni won ni ko mose
Osigbebo nbe orubo
Nje awo lara abi olara
Awo lara ejiogbe ara awo lose
Awo lara oyeku meji ara awo
Lose awo lara lodulodu ara awo leses Awo lara.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon sope
Oun oni eni kankan ki
Orubo ki awon eeyan le
Mon pesin laye re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye osin kan
Eyele m,erin
Eye etu meji
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Agbon lofidi jo oru
Adifafun bakahuya
Ose omo olokun seniade
Igbati nfomi oju sogbere ire gbogbo
Ebo ni won ni ko se
Osigbbo nibe orubo
Kepe kejina
Ewa bani ni jebutu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki orubo ki aje
Ole wawa pelu gbogbo nti obafe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele merin lebo
Eku
Eja
Pelu agbebo adie kan
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
OBARA OKANRAN
Obara kanhinkahin
Kanhinkahin womun
Adifafun kanhinkahin
Kanhinkanhin ntode orubo
Bo wa sile aye
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Kepe
Kejina
Ewea wo ifa awo ki biti nse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki elelyi orubo
Ki aye le ba tie mon
Yato larin aye
Ki osi rubo ki aye le mon beru re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele fun meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegunori eye kan nakanna eyo kan
Yio jo pelu ewe apada
Pelu odidi atare kan
Yose adura sio yio mon fi mu ko tutu
MEDICINE
Explore Ifa
Óbárà Òkánràn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Òkánràn Odu.
