Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifafun laseni
Omo ori ogboke tani lara
Igba nfomi oju sogbere ire
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ntori ire gbogbo
Ifa pe ebo ni yio gba kale
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyeetu meji
Akuko adie meji
Epo ati eko
Ese — Yoruba Verse
Ebo ni on ni kose igbati
Ko sebo ti ko se etutu
Nje kosi nkan kosi nkan
Ike ya dori eekan
Kosi nkan kosi nkan
Bata ya lorun ese
Kosi nkan kosinkna
Opo paaka wadi
Apero labe odan
Ese — Yoruba Verse
Adifafun ori nigaga nigogo
Igbati n torun bo wa saye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ori re ni okunkundun
Ki omon ki owo
Yepere min ori re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Fun ebo ruru
Epo ati eko
Ese — Yoruba Verse
Ewu ni ti inu ori wa
Olobara ni fi ile osa sona
Adifafun olobara ti se egbon osa
Igbati nsogbogbo arun
Ti nara kaka alaile dide
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe parunparun
Ewe segunsete
Aogunmon ose dudu pelu eerun
Alamo ao wa te iyere osun ni obara osa
Ao sure si ao mon we ni ale ti aba fe sun
Ao te iyere osun ni obara osa
Ninu opon ifa ao pe ifa si ao fi oti lo
Explore Ifa
Obara Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Obara Osa. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Oyeku, Obara Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Osa Odu.
