Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Olobara bobo bob
Adifafun ogongo
Ti n sa wo lo si
Isale akitan tin lola
Bawon gbofa ola tontomo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki osi rubo ntori omo
Ki nkan ti oba so fun ifa
Ki ole mon rine
Ki o si rubo ola pelu omo nbe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie toti pamori merin
Epo ati
Eko
Ese — Yoruba Verse
Adifafun orunmila
Baba obi tifase lomo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ba sofun toripe gbogbo
Nkan ti ifa ba so fun pata
Niyio se
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pelu epo
Eko
Kosi fi agbebo adie kan
Bo ifa re ki ifale gbo
Gbogbo nkan ti obasa opata
Ese — Yoruba Verse
Babalawo ekolo
Adifafun ekoklo
Igbati asunkun omo
Lo si isale abata
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ntori omo
Ifa sini ibi ti elleyi otifi
Olomo
Ifa pe ibi egbin ati
Iwosi ni yio ti olomo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pelu eyele meji
Epo ati eko
Lebo re.
Ese — Yoruba Verse
Arun oyo
Adifafun won ni idomun
Niniti won ti ntan ina roro
Le iku, arun, oto gbogbo ajogun lo
ISEGUN
Eni ti o fi sun ati idoti inu ile re
Yio fi gun ose pelu eeru alamon
Yo te ifa obaragbogbe yio se adure si dada
Yio mon fi we ni ojojumon
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Otapa yi po ile kosi gbon
Gbogbo lere jade patapata
Ntori gbogbo ajogun buruku
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pelu pepeye meji
Epo ati
Eko
Explore Ifa
Obara Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Obara Bogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Oyeku, Obara Iwori, Obara Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Ogbe Odu.
