Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ó

Óbárà Òtùrùpòn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/obara-oturupon
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Kafi igi lu igi Kale ba gbo ohun igi Kafi ope lu ope Kale ba gbo oun ope Kafi obara oturupon sode Kaleba gbo oun ti fa nwi Adifafun yeye kini nbe Nikunre igbati nfomi oju Sogbere omo Ebo ni won ni ki won ose Osi gbebo nbe orubo Nje eyin omope oyun adeyi Nibe nikun to dake sigidi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleye orubo Ntori omo ifa si ni omo Ti eleyi se bi yi okunrin ni omo naa Adeyi ni oruko re omon je

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meta Ni ebo pelu eku ati eja Eko ati epo pupa
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Obaratokutoku Adifafun won ni Itoku magbon ti isale oja Nibi ti won ti nko owo ra oko Ebo ni won ni ki won o se Won si gbebo nbe won rubo Nje ekowo wa ewa yan edu loko Akuko gagara oni kowo se Oko agbebo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo Ki won o le mon fi Ounrere wa kaakiri Papa bi oko tabi aya

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meji Akuko adie meji Eyele kan totobi Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Obara otokutoku Adifafun magbon ti sale oja Nibiti iku ti npa won rogba rogba Toku ti npawon rewerewe Bi eni pe won ji onje iku je ni Ebo ni won ni ki won ose Won si gbebo nbe won rubo Ero opo ero ofa eba ni Laiku gangidi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki won orubo si Inu ile tabi inu ilu Ntori ogun ki ogun mon ba Ka won mon le Ki iku mon ba mon pa won nikekere

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko lebo Ewure fun ifa Okete fun awon Agbalagba Eko ati epo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

OBARA OTURUPON Kafi igi lu igi Kale ba gbo oun igi Kafi ope lu ope Kale ba gbo oun ope Kafi obara oturupon meji lu Arawon kale ba gbo Nkan ti ifa nwi Adifafun orunmila Baba njaye elekoko bike Ebo ni won ni ko se osi gbebo nbe Oruko kepe kejina Ire gbogbo wa jede tutururu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo Ki omon ba jaye ele Ki ara ole ba de

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Lebo Kofi eran elede bofa Epo ati eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE Ewe saworopepe ao lo tio Kunna dada pelu iyere ao fi se eran Elede ti gesi 16 je lepo niyo Ao te iyere osun ni obara oturupon Ao se adura si dada Ao je gbogbo re. MEDICINE

Videos

Watch Óbárà Òtùrùpòn teachings on our channel.

Explore Ifa

Óbárà Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Óbárà Òtùrùpòn Odu.