Ó
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Kafi igi lu igi
Kale ba gbo ohun igi
Kafi ope lu ope
Kale ba gbo oun ope
Kafi obara oturupon sode
Kaleba gbo oun ti fa nwi
Adifafun yeye kini nbe
Nikunre igbati nfomi oju
Sogbere omo
Ebo ni won ni ki won ose
Osi gbebo nbe orubo
Nje eyin omope oyun adeyi
Nibe nikun to dake sigidi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleye orubo
Ntori omo ifa si ni omo
Ti eleyi se bi yi okunrin ni omo naa Adeyi ni oruko re omon je
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meta
Ni ebo pelu eku ati eja
Eko ati epo pupa
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Obaratokutoku
Adifafun won ni
Itoku magbon ti isale oja
Nibi ti won ti nko owo ra oko
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo nbe won rubo
Nje ekowo wa ewa yan edu loko
Akuko gagara oni kowo se
Oko agbebo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo
Ki won o le mon fi
Ounrere wa kaakiri
Papa bi oko tabi aya
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Akuko adie meji
Eyele kan totobi
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara otokutoku
Adifafun magbon ti sale oja
Nibiti iku ti npa won rogba rogba
Toku ti npawon rewerewe
Bi eni pe won ji onje iku je ni
Ebo ni won ni ki won ose
Won si gbebo nbe won rubo
Ero opo ero ofa eba ni
Laiku gangidi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki won orubo si
Inu ile tabi inu ilu
Ntori ogun ki ogun mon ba
Ka won mon le
Ki iku mon ba mon pa won nikekere
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko lebo
Ewure fun ifa
Okete fun awon
Agbalagba
Eko ati epo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
OBARA OTURUPON
Kafi igi lu igi
Kale ba gbo oun igi
Kafi ope lu ope
Kale ba gbo oun ope
Kafi obara oturupon meji lu
Arawon kale ba gbo
Nkan ti ifa nwi
Adifafun orunmila
Baba njaye elekoko bike
Ebo ni won ni ko se osi gbebo nbe
Oruko kepe kejina
Ire gbogbo wa jede tutururu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo
Ki omon ba jaye ele
Ki ara ole ba de
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Lebo
Kofi eran elede bofa
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ewe saworopepe ao lo tio
Kunna dada pelu iyere ao fi se eran
Elede ti gesi 16 je lepo niyo
Ao te iyere osun ni obara oturupon
Ao se adura si dada
Ao je gbogbo re.
MEDICINE
Explore Ifa
Óbárà Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Òtùrùpòn Odu.
