Ó
This Odu highlights the need for balance and harmony.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Obara mon tura sile
Ogun oba to lo
Adifafun orunmila
Baba ngbogun lo ibi
Atokedoke
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Kepe
Kejina
Ewa bawa bani laruse ogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Koni rubo
Ntori ogun to do ju ko
Ki o si mon fura dada
Nibikibi to ba n lo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie merin
Pelu epo pupa fun
Awon agbalagbal
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Igunnugun ba lorule
Oju tole ojutoko
Adifafun olofin agbodiwonran
Igbati nbe laarin osiri
Ti nbe laarin ota
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Ruru ebo
Eru atukesu
Okookan nifa o mon
Pa ota awo okookan.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ko rubo ntori
Awon ti won ngbogun ti
Ni ibi ti ngbe korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Pelu agbebo adie meji
Opolopo igbin fun oosa
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara tuatuatua
Babalawo enu
Adifafun enu
Njo ti nbe niro gun ota
Ebo ni won ni ko se
Osi gbebo nbe orubo
Nje nijo gbigbona egbewa
Nijo tutu e gbewa
Enu o sai munje gbe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo
Gbogbo ogun ti won
Ban gbe pelu re
Korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko lebo
Agbebo adie meji
Fun ifa bibo
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Erupuu babalawo odo
Adifafun odo
Egun saa babalawo olo
Adifafun olo
Ebo omo araye ni
Won ni ko se
Osi gbebo nbe orubo
Odoloun tisebo
Erupuu erupuu
Olo ni oun tise ebo
Eyun saa eyun saa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eni meji
Orubo ogun omo araye
Ki aye mon ba fi ogun mun won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Eyeetu meji
Ikode meta
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun
Eha ara odo eha ara olo
Ipepe irin eyo atare 9 fun okunrin
Eyo atare 7 fun obinrin
Gbere laari ori
Explore Ifa
Óbárà Òtúrá is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Òtúrá Odu.
