Ó
This Odu represents the need for careful planning and strategy.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ito bale ro gudugudu
Adifafun ikamundun
To nrogun ko leti
Ebo ni won ni ko se
Osi gbebo nbe oprubo
Kepe
Kejina
Eba ni laru se ogun
Aruse ogun laba ni lese obarisa
ASE K
Ki eleyi orubo
Ogun to fe ja
Ki o si rubo nkan ti ofeselesi
Ki ole ba segun na
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki elleyi orubo
Ki eni keji o mon gba
Ojuse re se nile ana
Tabi lenu ise re
Ki won mon gba nkan re
Mon lowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Okete kan fun awon agbalagba
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
OBARA OWONRIN
Obara moko so saja
Kasowo imele
Adigfafun olugbana omo
Asoko ola pa igba
Odidere
Igbati nfomi oju sogbere
Ire gbogbo
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Kepe
Kejina
Ebani ni jebutu ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon sope
Oun ko le je eeyan
Mon lailai
Ki osi mon se tutu
Dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Pepeye meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori pepeye meji
Ori alabahun meji
Odidi atare meji
Ewe segunsete topo dada
Ao jo papo
Ao te ifa re si ao se adura si
Ao mon fi foko tutut mun.
MEDICINE
Explore Ifa
Óbárà Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Òwónrìn Odu.
