Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Atare lose nu jinkun
Ora kan nikun atare
Adifafun esu legbe tise egbon monrari
Igbati won nroko allero odun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
se ase ju lodo eni ti notju re
pelu gbogbo nkan ti won nse fun
ifa pe ti oba ti ni aseju
yio pada si eni ete ni
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ki won oti bori won
Okete fi awon agbalagba
Epo ati eko
Akuko adie meji lebo
Ese — Yoruba Verse
Yeku yeku yekete
Adifafun odan
Odan nsawo losi ojuode
Ese — Yoruba Verse
Itan esin
Okere si nkanti agbalagba
Mon pede lelori
Adifafun olobara ti nsawo
Lo sile oyeku egbon re
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
eleyi ni oore re wa ko mon
se afojudi soro ebi rara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji lako ati labo
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Eeru ko eru louin osin oba
Iworiko oloun osinm ogba mon
Obinrin ko oloun ogba oorun oka
Oun mon
Adifafun bereri tise
Aya agboniregun
Ebo niwon ni kose
O si gbebo n ibe o rubo
Nje obara oyeku ta logbobeeri
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
MEDICINE
Explore Ifa
Obara Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Obara Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Iwori, Obara Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Oyeku Odu.
