Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ó

Óbárà Ósà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Obara Osa
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of vigilance and awareness.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/obara-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Obara Osa

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Olobara saka sare Adifafun laseni Omo ori ogboke tani lara Igba nfomi oju sogbere ire Ebo ni won ni ko se Osi gbebo nbe orubo Kepe kejina Ewa bani jebuture

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo Ntori ire gbogbo Ifa pe ebo ni yio gba kale

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele fun meji Eyeetu meji Akuko adie meji Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Obara saka sare Adifafun ori nigaga nigogo Igbati n torun bo wa saye Ebo ni won ni kose Osi gbebo nbe orubo Nje ori ni gaga nigogo Ogaga ngogo iwo lawo ori

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Eleyi gbogbomun Ori re ni okunkundun Ki omon ki owo Yepere min ori re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu ni ofi bo ori re Akuko adie meji Fun ebo ruru Epo ati eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ewe parunparun Ewe segunsete Aogunmon ose dudu pelu eerun Alamo ao wa te iyere osun ni obara osa Ao sure si ao mon we ni ale ti aba fe sun Ao te iyere osun ni obara osa Ninu opon ifa ao pe ifa si ao fi oti lo

Videos

Watch Óbárà Ósà teachings on our channel.

Explore Ifa

Óbárà Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Obara Osa. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Óbárà Ósà Odu.