Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Obara Okanran

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/obara-okanran
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Bi babalawo gbofa
Bi ogbofa eje kafi
Obara okanran lowo
Obara okanran
Kise ifa afi lande
Adifafun orunmila baba nsukun
Alailenikankan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon sope
Oun oni eni kankan ki
Orubo ki awon eeyan le
Mon pesin laye re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye osin kan
Eyele m,erin
Eye etu meji
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Bi mo leku kinku
Obara okanran
Bi molerun ki nrun
Obara okanran
Adifafun gudugudu
Tise omo leyin bata

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki orubo ki aje
Ole wawa pelu gbogbo nti obafe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin lebo
Eku
Eja
Pelu agbebo adie kan
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Obara kanhinkahin
Kanhinkahin womun
Adifafun kanhinkahin
Kanhinkanhin ntode orubo
Bo wa sile aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki elelyi orubo
Ki aye le ba tie mon
Yato larin aye
Ki osi rubo ki aye le mon beru re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji
Eyele fun meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

OBARA OKANRAN
Bi moleku ki n ku
Obara okanran
Bi mole run ki nrun
Obara okanran
Adifafun kanna kanna
Kan na kanna n torun bo wa saye

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Isegunori eye kan nakanna eyo kan
Yio jo pelu ewe apada
Pelu odidi atare kan
Yose adura sio yio mon fi mu ko tutu
MEDICINE

Videos

Watch Obara Okanran teachings on our channel.

Explore Ifa

Obara Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Oyeku, Obara Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Obara Okanran Odu.