Ó
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Olobara sekun sesubu
Adifafun amon roro afeje we
Igbati nbe laari osiri
Ti nbe laarin ota
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Kepe
Kejina
Eba ni laruse ogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eni ti pupa osora
Ni asiko ti o da ifa yi
Ntori ogun omo araye
Kosi rubo ni isegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele funfun meji
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ewure awo ilu telu
Agutan bolojo awo ilu tayo
Adifafun onidoko ate
Igbati ntomi oju sogbere omo
Ebo omo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Ruru ebo
Eru atukesu
Ewa bani ni jebutu omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Komo je ki etutu
Osuu oun lori nkan
Ti ondafa si
Ifa pe oti gbiuyanju dada
Sugbon nkan ti ondafa si ko ti se
Ifa ni akoko ti to bayi ti yoribosefe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie merin
Eye etuy merin
Eyele merin
Epo ati eko
Pelu obi
TRANSLATION Goat el
sacerdote de Ilu telu
La gran oveja, el sacerdote de Ilu Tayo Adivinación de ifa para Onidoko ate Cuando lloraba por tener un hijo
Se le pidió que ofreciera el sacrificio
Y él cumplió
Ofrenda de sacrificio
Sacrificio completo
Ven a conocerme en el dominio de la maternidad
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara semi sepepe
Babalawo aayan
Adifafun ayan
Aayan nlo le re adie leru
Ebo ni won ni ko se
Igbatu ebo
Igba tu eru
Eru ta kowo ra se tu pani
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo
Ko mon je pe nkan ti o ba
Ko owo ara re na niyi opa
Korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Eyele funfun meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Obara Sekulukulu
Babalawo omi
Adifafun omi
Omi ntorun bowa saye
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje tomi ba bale omi alapo
Bi agbara ba bale ala ilu ja
Bomi ba bale alapa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe eleyi
Olobo osun dada
Ti o ba siri pe ojo nro
Ko ripe ojo na ro pa die
Ki o mon ba jaye ele koko mon
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Adie agada kan
Fun osun ati obi
Agbebo adie kan fun
Ebo ruru
Eyele meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun
Ogbe ori akuko
Tiwon ti rubo yen
Pelu eyo atare 9 fun okunrin
Eyo atare 7 fun obinrin
Gbere laarin ori fun isegun
Explore Ifa
Óbárà Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Òsé Odu.
