Ó
This Odu highlights the need for courage and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Obara eguntan
Ori isin yo isin
Adifafun olori iranhunran
Ti ntorun bo wa saye
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje fori re ranmi ki nlaje
Olori iranhunran
Fori re ran mi ki nire gbogbo
Olori iranhunrani
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki elelyi omon bo
Ori re dada ki ole mon
Sanu re de ibi ire ti obafe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu ni o fi bori se
Yio fi akuko adie rubo
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Obara eguntan
Ori isin yo isin lomi
Ori okasa asi mon yo
Okasa lodo
Adifafun esi ejide
Ti nfomi oju sogbere omo
Ebo ni won niko se
Osi gbebo nbe orubo
Kepe
Kejina
E bani ni jebutu omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eleyii pe ki o mo se afojudi
Ki ole badi olomo
Ki osi mon ko egbin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Agbon fi orire
Eku
Eja
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe sefunsefun ao lo ti o kuna dada ao fi omi inu agbon po aofise eyin ororo merin je lepo niyo aote iyere osun obara ogunda ao se adure si ao je
MEDICINE
Explore Ifa
Óbárà Ògundà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Ògundà Odu.
