Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ó

Óbárà Ìrètè

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of patience and persistence.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/obara-irete
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Olobara reterete Babalawo oka Adifafun oka alawo bobo Ekun omo nisun Ebo omo araye ni won ni ko se Igbai sebo Igbatu eru Eyin ori ifa tawo ki bitin se Ifa de alase ope abise waraware

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o gbo oro ti Awon babalawo ba so Ki o si fi aso re Alawo orisirisi ko firubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aso alaranbara Akuko meji Epo Eko Ori oka lebo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Obara reterete Babalawo omi Adifafun omi Igba ti ntori bo wa saye Ebo ni won nikose Osi gbebo nbe ori Nje tomi babale Omi anipa Bi agbara ba bale Ala iluja Bomi babale omi anipa ESE Ko rubo ko leba Nipa ire laye Ki aye mon dowo Bo ogo re mon

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igbin pupo Eyele meji Epo ati eko Agbebo adie
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Peegun loruko tape oka Peregun loruko tape ere Olobara beekube loruko tape igbin Adifafun alaso dudu oke ape Igbati nfomi oja sogbere omo Ebo won ni kose Osi gbebo nbe orubo Nje olobara gigi kan osi o Omo eni ni alawo jinji eni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ki elelyi korubo Ntori omo ki o mon Badi eni ti ko ni ni Omo laye mon

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meji Pelu igbin merin Akuko adie kan Fun ebo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Igunnugun bale Ose gu o Adifafun olobara Ti n lo lee te irete nifa Ebo ni won ni kose Osi gbebo nbe orubo Nje olobara pele Omo iya irete

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe omo iya eleyi Ni yo se laanu ti yi o fi di Eniyan pataki lawujo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin Pepeye merin Epo ati eko

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Koni igi nla ko fi ewe parunparun Kun ko wa gun papo mon imi ojo kosi Eru pe ifa re obararete Ki o mo se adura si ki o to mon fi para ao da sinu ipara ti o ba loorun

Videos

Watch Óbárà Ìrètè teachings on our channel.

Explore Ifa

Óbárà Ìrètè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Óbárà Ìrètè Odu.