Ó
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Obara ka kise oun te
Baba lawo ti n be nibe
Ni o gbofa
Adifafun alakan ti n lo
Eti okun lobi yaya lomo
Ebo ni won ni ko se
Osi gbebo nbe orubo
Ero opo ero ofa
Ewa bawa ni jebute omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo ntori
Omo ifa si ni pe
Ibi eti omi ni omo wa
Fun eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie merin lebo
Eyele merin lebo
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ojo oganjo
Ni ta ogiri sasas lese
Adifafun tisan
Ti nlo le bo lowo ogun
Ebo ni won ni ko monse
Osi gbebo nbe won rubo
Nje mono lowo ogun ni gfbyi o
Mobolowo ogun
Agbala esin bo lowo
Aru eru monso
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo
Ntori ogun omo araye
Ifa pe ogun nja
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Okete meta
Agbebo adie meta
Ao fi eku ati eja pelu agbebo adie bofa Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara ka ki se oun te
Baba lawo ti nbe nibe
Ni o gbofa
Adifafun sango olukoso laalu
Banbi arigbota osegun
Igbati nbe laarin ota
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo orubo
Nje kin larire fi sete
Igba ota egberin amonla
Larira fi sete
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o se etutu
Aseyori ninu aye ki aye
mon ba mon da laamu ju
Kole ni isegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie fun sango
Agbobo adie fun ifa
Pelu eku ati eko
Epo ati eko
Akuko adie fun ebo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
OBARAIKA
Firifiri ni won roju egungun
Adifafun olobare
Ti se omo iya ika
Igbati won nlo oko ailero odun
Ebo ni won ni ki won ose
Won si gbebo nbe won rubo
Ero opo
Ero ofa
E abani
Laruse ogun aruse ogun
Labani lese oba orisa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki omo iyameji
Orubo ntori ogun tofe
Ko won papo lekan naa
Ki won si mon se
Aigboro sirawon lenu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko lebo
Pelu okete fun
Awon agbalagba
Epoati eko
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Yepe ipile ile ao lo pelu atare eyo 9 fun okunrin meje 7 fun obinrin ato ni obara ika ao a pe oun re si ao fi sin gbere si orikerike ara wa.
Explore Ifa
Óbárà Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Óbárà Ogbè, Óbárà Òyèkù, Óbárà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Óbárà Íká Odu.
