I
This Odu signifies the importance of adaptability and flexibility.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Enu awo nije irinwon eku
Enu awo nije irinwo eja
Iwori oderin monjo lofa
Asise nifi inu sele
Nifi eyin sede
Adifafun ajijobi
Tii se omo bibi inu agboniregun
Ebo ni won ni ko mon se
O si gbebo nibe orubo
Nje, ifa mon jeki ajijobi oku o
Ipabi awo ki ku boroboro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori emi re, ki o mon fi eku ati eja bofa re pelu obi ki o si mon je esebi ti owa lori ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Agbebo adie
Obi
Akuko adie meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Eeru awo kulo
Elu awo ode obaramonje
Opa aro nifidi pa ayinrin
Adifafun olorubu okejo
Okanla abori yebeyebe
Igba ti nbe laarin ajogun omo araye
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe orubo
Nje esunmi o eyin
Afaimo ni sunni
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon pese fun awon agbalagba dada ki won le mon fi ori fi ese re jin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Okete kan
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Enu awo nije irinwo eku
Enu awo a je irinwo eja
Iwori ni obewe kotorogun owonrin
Adifafun orunmila
Baba ngbogun rebi atoke doke
Ebo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Kee pe
Kee jinna
Ogun tawo baja
Ajasegun moni o
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ogun kan nbe niwaju eleyi, korubo ko le ba a segun naa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
oruko kan
Obi
Epo pupa
Akuko meji
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Opa aro nifidi payinrin
Adifafun olofin
Ti nsogbogbo arun
Ti nara kaka alailadide
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje ogbo agborako
Logbo alabahun
Adagbarako ni ti igbin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo ajinde ara ko mon rubo nitori aare
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Alabahun meji
Igbin to pinu meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori alabahun kan tafi rubo
Odidi atare kan totobi dada
Aojo papo ao fi si gbere si aarin
Lori koniye
Explore Ifa
Iwòrì Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwòrì Òwónrìn Odu.
