I
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori gosun gosun
O sowo odo poroporo
Adifafun agan oribi
Ti n fomi oju sogbere omo
Ebo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Keepe
Kee jina
E wa bani ni jebutu omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni ki eleyi orubo nitori omo, ifa pe agan kan wa ni egbe eleyi ki o bo ifa nbe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie merin
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Mon gooro mon gooro nla si fon
Mon farara mon farara nla si wriwo
Adifafun olosun
Tiise Aya agboniregun
Igbati nofo mi oju sogbere omo
Ebo omo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Nje iwori mon ka osu mon
Oyun ni olosun nnihun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe enikan se awari omo ti o si ti fe sodi eni yepere lawujo ki orubo asiko ti yio ni oyun ni o de yi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure kan
Obi
Epo
Eko
Agbebo adie meji
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
keke ni ofi ijo sowo se
Adifafun moni omo alara
Kaka ni o fijo sowo se
Adifafun mon sun omo awujaile
Adifafun orunmila
Baba n lo lee gbe monsun omo awujailwe niyawo
Nje iwo to fe monsun niyawo
Iwo lo wa oran aisun
Iwo lo wa oran aiwo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ki eleyii
omonse aigboro si ifa lenu
ko gba nkan ti ifa ba wifun
ifa ope nkan lofe se yi
ki o bere lowo ifa dada
koto se
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie merin
Eyele funfun merin
Epo pupa
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori gosun gosun
O sowo odo poroporo
Adifafun orunmila
Baba oni owo kan ayona
Ebo aje ni won ni kose
Osi gebo nibe orubo
Kee pe
Kee jina
E bani ni jebute aje suuru
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe eleyi n sunkun aje ki eleyii orubo ntori aje
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo ogede omini
Eyin ati
Eyele funfun merin
Obi
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ki otoju ewe sajeje kolo kunna dada kosi se eyele funfun kan lepo niyo pelu iyere ki owa te iyere osun ni
Explore Ifa
Iwòrì Íròsùn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwòrì Íròsùn Odu.
