Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Eni aja bawa laja balo
Adifa fun Orunmila
Ao toju ewe awo yoyo ati owu alahunla ao wa gun mon Ose dudu eni naa yio won fi we
ISEGUN
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eja meji
Abodie meji
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Oku subu lagba
Adifa fun soreyo
Ti n momi oju sogbere omo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Owo
Ese — Yoruba Verse
Ti yo ma soohun gbogbo bidan bidan
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Owo
Ese — Yoruba Verse
Oloda omon kin ode labokore
Komon raunro peti
Adifafun ode gbahunsasa
Ti suku pe oun koni eni kan
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eja kan
Abodie kan
Epo
Eyin
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Iwori Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Meji Kinni. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi, Iwori Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Meji Odu.
