Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Iwori Odi

Iwori Odi

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Iwori Wodin
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/iwori-odi
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Wodin

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni patie tere
Ni mun egungun wogbo
Atori agbadagi ni min oro
Wo igbale
Adifafun osu hunlaya
Ti se aya agboniregun
Igabti nmomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyi o lobo egungun nitori omo ki oni opolopo atori si idi egungun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji
Pelu eyele
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni oju mon on
No gbo poroporo odo
Aajin jin no gbo
Woyo woyo konoso
Afai mon kawo ko mon sun lebi
Adifafun iwori ti n lowo odi nisoju ebi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyiii o mon je ki ebi o mon pa oun ki oto mon jeun ki o mon jeun ni asiko

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo ounje
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni bai laselu
Ilu iba dun
Bai laselu
Ilu iba yun
Adifafun iwori ti n lo wo idin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki omo iya meji o fi ife barawon se papo ki gbogbo nkan ti won ba dawo le ko le se si dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eeyele merin
akuko adie merin
epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

IWORI WODIN
Patie teere
Ni sawo fun egungun
Adifafun agandi
Ti nfomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyi o lobo egungun nitori omo ki oni opolopo atori si idi egungun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan

Eko

Oole

atori fun egungun

Agbebo adie meji

Epo

Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ewe segunsete pelu eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao mon we ni osan ni dede agogo kan osan

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ewe segunsete pelu eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao mon we ni osan ni dede agogo kan osan

Ewe aje topo ewe saworopepe to po dada ao fi se edo maalu ti a ge si (16) tepo ni yo je aote iyere osun ni odu ifa iwori wodin

Videos

Watch Iwori Odi teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwori Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Iwori Wodin. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwori Odi Odu.