Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Iwori Ose

Iwori Ose

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/iwori-ose
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori wowo wowo
Ifa ni wiro wokun wokun
Iwori wokun tan
Koto wode
Adifafun enlojo agan
Ti ntorun bo wa saye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe awon ni ti won nwa omo ifa pe ebo ni ki eleyi o mo rukole ba di olomo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo igbin
Agbeboadie merin
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Iwori wese wese
Adifafun Aase mon gamonga
Ti won ni ko rubo
Ogun omo araye
Igba aitubo
Igba aiteru
Eri ifa awo ki bi ti n se
Ifa de alase ope abise warawara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo laarin opolopo awon ti won jo nse nkan papo ti o mon je pe ti e ni o ni gbayi lawujo awujo awon joku

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji
Eyele meji
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Iwori wowo wowo
Iwori wokun wokun
Adifafun won ni Isese Asere
Ibi ti won ti moju owo ju omo lo
Eyin pele ara isese asere
Te mon oju owo ju omo lo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon mon oju owo ju omo lo Ifa ni omo ni yio la
eleyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji
Eye etu meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Aba awo ile Oniseri
Adifafun oniseri
Ni kutukutu awuro
Igbati nfomi oju sogbere
Ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire ola fun eleyi sugbon ko mo deja nkan ti won basofun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji ebo
Eyele meji ebo
Akuko adie meji fun ebo
Epo
Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE
Ewe adosusu aolo pelu iyere ao fi se eja ajabo kan lepo niyo ao te ifa iwori wowo sinu opon pelu iyere osun ao se adura si ao je gbogbo re pata.

Videos

Watch Iwori Ose teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwori Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwori Ose Odu.