Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifafun efufu lele
Ti o ni oun o mun oun
Ile je gbe
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Babalawo ekolo
Adifafun ekolo
Ngbati nlo isale abata
Nitori omo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ntori omo ko le badi
Olomo laye
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele funfun meji
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Ejeka to wo bi aba
Ri ire nibe
Adifafun iwori ti nlole ree ko ire ba ogbe egbon nile
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki won o si mon ja arawon niyan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie meji
Epo at eko
Ese — Yoruba Verse
Iwori bogbe ni ji je
Iwori bogbe ni munmu
Adifafun igunnugun
Ti nlo wo adaba lorun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Fun awon agbalagba
Odidi oruko kan
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju ewe ajilekese ti o po dada egbo feru ao gun mon ose dudud aote iyere osun ni iwori bogbe
Ao se adure si ao mon fi we lori okuta ako ni ojo ketaketa
Igbin to pinu merin, ewe sajeje topo ewe adurosusu, ao lo pelu iyere ao fi se igbin yen lepo niyo je, ao te iyere osun ni oduifa iwori bogbe ao je ti abafe sun lale.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao se adure si ao mon fi we lori okuta ako ni ojo ketaketa
Igbin to pinu merin, ewe sajeje topo ewe adurosusu, ao lo pelu iyere ao fi se igbin yen lepo niyo je, ao te iyere osun ni oduifa iwori bogbe ao je ti abafe sun lale.
Explore Ifa
Iwori Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Bogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Oyeku, Iwori Odi, Iwori Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Ogbe Odu.
