Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Iwòrì Òdì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Iwori Wodin
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/iwori-odi
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Wodin

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni patie tere Ni mun egungun wogbo Atori agbadagi ni min oro Wo igbale Adifafun osu hunlaya Ti se aya agboniregun Igabti nmomi oju sogbere omo Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Ero opo Ero ofa Ewa bani laarin omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyi o lobo egungun nitori omo ki oni opolopo atori si idi egungun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji Pelu eyele Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni oju mon on No gbo poroporo odo Aajin jin no gbo Woyo woyo konoso Afai mon kawo ko mon sun lebi Adifafun iwori ti n lowo odi nisoju ebi Ebo ni won ni ko se Ero ipo Ero ofa Iwori ti se wodi nsoju ebi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyiii o mon je ki ebi o mon pa oun ki oto mon jeun ki o mon jeun ni asiko

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo ounje Akuko adie meji Eyele meji Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni bai laselu Ilu iba dun Bai laselu Ilu iba yun Adifafun iwori ti n lo wo idin Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Nje, bai laselu ilu ibadun Bai laselu ilu ibayun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki omo iya meji o fi ife barawon se papo ki gbogbo nkan ti won ba dawo le ko le se si dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eeyele merin akuko adie merin epo ati eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ewe segunsete pelu eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao mon we ni osan ni dede agogo kan osan

Videos

Watch Iwòrì Òdì teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwòrì Òdì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Iwori Wodin. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Íròsùn.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwòrì Òdì Odu.