Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Iwori Meji

Iwori Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Iwori Meji Kinni
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
Iwori Meji indicates a period of deep insight and self-awareness. It brings heightened understanding of oneself.
Listen
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/iwori-meji
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Meji Kinni

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Eni abawade laba rele
Eni aja bawa laja balo
Adifa fun Orunmila
Ao toju ewe awo yoyo ati owu alahunla ao wa gun mon Ose dudu eni naa yio won fi we
ISEGUN

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifani ki eleyin o rubo kole bami aje lowo papa julo kio mo ju tofa dada pe orun ifa lowa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji
Eja meji
Abodie meji
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Agba subu loku
Oku subu lagba
Adifa fun soreyo
Ti n momi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nip e ohun pe ire omo fun eleyin pe oju omo ni pon eleyin ebo omo ni kose

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewure Kan
Epo
Eko
Obi
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ogodo gboke odo payin keke soloko Adifa fun alahuntakun
Ti yo ma soohun gbogbo bidan bidan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa niki eleyin orubo ola pe oju aje ni pon eleyin ebo ni koru ki won osin se 0ifare hfun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan
Epo
Eko
Obi
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Singin yi siginlohun
Oloda omon kin ode labokore
Komon raunro peti
Adifafun ode gbahunsasa
Ti suku pe oun koni eni kan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin orubo kole bani omi, sin pe eye won eleyin tabi oju owo pe ebo ni koru kole badi olorun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan
Eja kan
Abodie kan
Epo
Eyin
Obi

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao mu yanrin oju ode ati ewe gbegi ati ewe segun sete ao wa jo gbogbo re pepo pelu ataare kan ao wa mon fifo eko tuntun won larolaro

Videos

Watch Iwori Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwori Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Iwori Meji Kinni. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi, Iwori Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwori Meji Odu.