Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Iwòrì Íròsùn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/iwori-irosun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori gosun gosun O sowo odo poroporo Adifafun agan oribi Ti n fomi oju sogbere omo Ebo ni won ni ko mon se Osi gbebo nibe orubo Keepe Kee jina E wa bani ni jebutu omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni ki eleyi orubo nitori omo, ifa pe agan kan wa ni egbe eleyi ki o bo ifa nbe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie merin Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Mon gooro mon gooro nla si fon Mon farara mon farara nla si wriwo Adifafun olosun Tiise Aya agboniregun Igbati nofo mi oju sogbere omo Ebo omo ni won ni ko mon se Osi gbebo nibe orubo Nje iwori mon ka osu mon Oyun ni olosun nnihun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe enikan se awari omo ti o si ti fe sodi eni yepere lawujo ki orubo asiko ti yio ni oyun ni o de yi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewure kan Obi Epo Eko Agbebo adie meji
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

keke ni ofi ijo sowo se Adifafun moni omo alara Kaka ni o fijo sowo se Adifafun mon sun omo awujaile Adifafun orunmila Baba n lo lee gbe monsun omo awujailwe niyawo Nje iwo to fe monsun niyawo Iwo lo wa oran aisun Iwo lo wa oran aiwo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ki eleyii omonse aigboro si ifa lenu ko gba nkan ti ifa ba wifun ifa ope nkan lofe se yi ki o bere lowo ifa dada koto se

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie merin Eyele funfun merin Epo pupa Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori gosun gosun O sowo odo poroporo Adifafun orunmila Baba oni owo kan ayona Ebo aje ni won ni kose Osi gebo nibe orubo Kee pe Kee jina E bani ni jebute aje suuru

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe eleyi n sunkun aje ki eleyii orubo ntori aje

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo ogede omini Eyin ati Eyele funfun merin Obi Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ki otoju ewe sajeje kolo kunna dada kosi se eyele funfun kan lepo niyo pelu iyere ki owa te iyere osun ni

Videos

Watch Iwòrì Íròsùn teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwòrì Íròsùn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwòrì Íròsùn Odu.