Ò
This Odu highlights the importance of introspection and self-awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Iwori wotu peerepe
Adifafun keke
Tii se omo iye olomijo
Iwori wotu peerepe
Adifafun okoto tise
Omo iye olomijo
Ebo ni won ni ko se
Won si gbebo nibe won rubo
Nje oro wa dijo dayo peerepe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki omo iyameji o rubo aseyori lori ise won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Pepeye meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Iwori wotu
Peerepe
Adifafun okoto
Okoto nlo eti okun lojo
EBO ni won ni ko mon se
Igba aitubo
Igba aiteru
Eyin o ri ifa awo ki biti nse
Ifa de alase ope
Abise wara wara
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii o mon lo ode ijo ni ojo meta yii ki o si gbo ikilo ti awon awo ba so fun dada o
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Eyele meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Eyi gbalanja bi abere
Eyi minijo bi ikokun
Adifafun orunmila
Baba nbe laarin ota
Sangiliti ebo ni won
Ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Kee pe
Kee jina
Ewa ba wa laruse ogun
Iwori were
Babalawo ata
Adifafun ata
Igbati nfomi oju sogbere omo
EBO ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Ewa bawa laarin omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo isegun ota, Ifa pe aarin ota ni eleyi wa korubo
Ki eleyi orubo nitori omo ki osi rubo ki araye o mon pa omo reje
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Okete kan
Epo
Eko
Agbeboadie meji
Okete
Akuko adie meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori wo tu peerepe
Adifafun elegiri
Igbati nsaye loun nikan
soso girogiro
Ebo ni won ni ko mon se
O si gbebo nibe orubo
Nje eeyan logun elegiri
Awo aboju kotokoto koto
Babalawo AJE
Adifafun AJE
AJE ntorun bo wa saye
EBO ni won ni kAJE ose
Nje AJE de oni so
Fi so sile awo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki orubo ki o mon bada se ile ayere ki o ledi eni apesin
Ki obo aje ki aje ole duro ti
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Opolopo igbin
Epo
Eko
Eyele funfun
Eye etu meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Awo etu, egbotude odidi atare kan, ao go papo ao mon te ni odu ifa iwori wotupere
ISEGUN
Epo ata ijosi aoloti o kunna
Dada ao po po mon ose dudu
Ao ko sinu poko agbon
Ao mon fi fo owo wa larolaro
Ao mon so nkan ti abafe si
Explore Ifa
Òtúrá Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Òtúrá Ogbè, Òtúrá Òyèkù, Òtúrá Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òtúrá Iwòrì Odu.
