Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Ologberi n so
Ogberi o mo pe eni awo sin oju olowo lo
Adifafun awodi owosa
Ti n lo lee wofa okin ni karo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo ikode
Omirin ake
Opolopo Owo
Ori lopolopo.
Ese — Yoruba Verse
Lodifafun odugbe
Odu n lole ba won da oko eba ona
Otua kaka ka
Adifafun kokoja
Ti n lo lee fe mo lodo kokokun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifayi ko rubo ki omo araye o ma ba konu re ifa ni obinrin ni eleyi fefe yi ifa ni awon to fefe omo won won yii ju lo ko rubo kole ba fe omo na.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin
Abo adie
Opolopo owo
Agbebo adie
Akuko adie
Opolopo adun
Eyele
Igbin
Aso funfun
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Awo ile onijan
Adifafun alukutu
Tii se ayo onijan
Otua kun ka dagbo
Ologbe ri o mo
Ologberi iba mo
Iba fi le ka sododo
Adifafun Ajee
Ti n torunbo waye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifayi korubo ifa ni oju ajeni pon eleyi korubo ki aje o le ba to lowo ko si rubo komo bari idamun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Akuko adie
Opolopo owo
Eye etu
Eyele
Pepeye
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun olodi amojinan
Eku onile eni fada
Adifafun bale ni seke
Omo a fi ebo segun
Igba ti n be lagbaka omo araye
Otuakunka o firoko sonan
Adifa fun oluwoo oduro
Ti o tule fun olowuroko
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifa yi ifa ni eleyi fe se oore fun orere kan koma se ki oore yi ma bajulo tabi ofe kowole nkan kan ki won o fi iranse bi fa ti fa bani o se ni ko se o tifa ba ni o ma se ko mo danwo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
Akuko adie
Eyele
Opolopo owo
Eye etu
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Egbo meruwa afara oyin ipe oore ao da oti sile ao fi pa eesin ti yo po dada ao wa gun po mo ose ao ma fiwe laro laro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo emina egbo efinrin alupaida ao jo pomo odidi atare kana o ma fi fo eko tutu mun laro laro
Explore Ifa
Otura Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Otua Osa. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Otura Osa Odu.
