Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Roko wooroko woorooko lalagbede ro
Ada lejida lejida ni won ro agogo nde ni morun aiku
Adifafun abiba ti n lole pon atiipon lorun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie
Akuko adie
Eye Etu
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun akan
Tii se omo onibu
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni korubo ki ire ole ba to lowo ko si maso pe oun ko sin ifa mo o ko si ma da oko
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie
Pepeye
Opolopo owo
Akuko adie
Eyele
Agbebo adie
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Emi o je figun orunla
Ate timo fipa te ileke
Emi o je fi pate egusi
Adifafun kerensele omo olodumare
Omo ateni lege lege fori sapeji omi
Igba ti n torun bowaye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun enitoda ifayi ki eleyi orubo nitori iku kosi mo ra inkan atuta ko si mo oun ti babare o gba to won ba sip e in bi kan komo lora kotode ise
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie
Igbin
Gbogbo oun tenuje
Opolopo owo
Akuko adie
Agbo kan
Eye Etu
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Kowojo wojo
Adifafun otua
Omo araba le domo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifa yi ifa ni oun ri ire aiku ki a rubo ki ire aiku o le jale ifa ni won kan robi si ni bikaku bikaku sini karubo kasi fi agogo kun ebo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igin
Eye Etu
Opolopo owo
Agogo
Akuko adie
Igbin
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Eso konun koho awoo ejo eyi keyi ewe aje toni inalori dada ao lopo ao fi se eyele meji leponiyo ti o bajinan dada ao wa se adua si ao wa koja
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Oromoadie kan ewe abirikobo odidi atare kana o jo po mo arawon ao wa po ose dudu mo ao ma fi we pelu kanhin kanhin tutu laro laro
Explore Ifa
Otura Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Otua Obara. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Otura Obara Odu.
