Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun otua
Eyi ti yio ran ahun meji
Ti yio lapere gede
Ao toju eweanu ao lopomon iyere ao fi se odidi alabahun Kan lopo ni yo ti aba se tan ao se adara si ao wa je ni oru gaujo.
ISEGUN
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun kekere omo binrin isin
Abu fun agba omon kunrin isin
Igba ti won momi oju sogbere omo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Obi
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun Orunmila
Eleyii ti won o mu je olori abonmonle nife
Igba ti won ni korubo ni laiku arare
O si gbebo nibe orubo
Nje iku oni pa olori abamonle ni fe
Ajosiki ode awo imonran
Arun ko ni so lori abo monle nife
Ajosikin ode awo imonran.
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Isu pupo
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Obi lobi imonran
Emu lemu ara jonjo
Adifa fun kekeke ipapo
Abufun agba ipapo
ijo ti won jasile
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eja aro meji
Epo
Eko
Obi
Oti
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Otura Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Otua Meji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori, Otura Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Otura Meji Odu.
