Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Otura Ofun

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Otua Ofun
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of balance and harmony.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/otura-ofun
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Otua Ofun

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Aparun singin
Emere singin
Adifafun Oolo emere orun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa ni eleyii sun orun korun, o si n la alakala, ifa ni apere iku ni ko rubo, ko si rubo fun odidi ojo meje nitori iku.
Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa ni ninu awon omo teleyii bi, okan ga ju awon egbon re lo, ko rubo fun un nitori iku, ifa ni ibi aye se n wu bee ni orun n wu.
Ifa pere fun eni to da ifa yii, ifa ni ki eleyii o rubo ki ire o le de fun-un, ifa ni eleyii ti n damu, ifa ni ori re ni ko bere oun ti ori re o gbaa, ko fun
Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa ni ki eleyii o rubo, ifa ni toba je pe obinrin ni eleyii fee fe ni ko fe ti ifa ko mo je pe ounni o ma sin obinrin naa tabi to baje pe eleyii fe ra nkan ni, ko rubo ki nkan to ba ra naa ko ma je agbana fun un.
Ifa ni laarin ota leleyi wa korubo kolebaa segun awon ota eleyii n wa isubu re, ifani yio ba seegun paa paa julo ibikan lo fe loyii korubo koto lo koman baa je pe oku le yini won yio gbebo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko
Akuko
Opolopo owo
Oruko
Akuko
Opolopo owo
Akuko adie
Pepeye
Eyele
Agbebo adie
Opolopo owo
Akuko adie
Agbebo adie
Eye etu
Eyele
Opolopo owo
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Aparun singin
Emere singin
Adifafun eemere
Iya e ti o gaju agan re lo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ota po feleyi ibikan si leleyin lo yi korubo kotolo ko le baa de nitori awon ota ti lo tele de eleyi sile nimbi tin lo ki eleyi osi mansin olongbo ti awon ota batinri ologbo yi won o man sa feleyi
Keleyi orubo aarin ota lowa, ifa loun o ba segun ota eleyi eni to gban gidi gidi ni o sugbon ki eleyi oso oro enun re nitori won o man lu lenun gboro

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Akuko adie kan
Owo
Epo
Eko
Agbado
Owo
Kengbe kan
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oro biyan biyan
Oro bi oka bi oka
Oro bi kengbe
Emun defun defun
Adifafun ori ti n gboko mesun aburo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ire aje feleyi, korubo kosifi oyin bofa kire ajere olode ni tori gbogbo ire ti eleyin wa odo ifa lowa, ko si tun fi oyin rubo, ki oro eleyi ole dun bi aye oyin.
Ifa loju ajen pon eleyi keleyi orubo Ajenbo feleyi gbogbo oore ti eleyi ri okan foju ri ni kote lowo sugbon keleyi orubo ni ki oore re ole baa tee lowo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Eyele meji
Owo
Oyin
Epo
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Elepo nifa kara se
Adifafun owo
Ti n lo le gbe nanmu niyawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi o man bo fa dada ifa ni ounyio la eleyi, ki o si fi ounje to ba dara bo ifa re pelu oti to dara pelu obi ati owo, ki eleyi osi man se ose fun ifa re kole ba di eni ti aye o man pesin.
Ifa ni beleyi bati ji, ko man fori kanle Faje aje yio wa joko ti eleyi keleyi ofi eye bo aje ni tori gbogbo bi eleyi sen gbi yan ju to aje oya sodore sugbon asiko ti to bayii tire aje re de.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi onje oti obi bofa
Epo
Eko
Agbado
Ekuru funfun
Eyele kan
Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

(PARA LA RIQUEZA)
La semilla de apa que cayo por si sola, un pescado grande y seco tipo abori con manteca de karite y molido con jabon negro y empacado en una olla de barro y la persona se bañara con el muy temprano en la mañana antes de hablar con alguien o en un lugar oscuro.
(PARA LA VICTORIA)
El eko kolobo Hierbas ewe eko kolobo con un lagarto agama se quemaran con un pimiento completo de cocodrilo y la persona lo tomara con Eko frio todas las mañanas.
AJE
Ewe etipon ola, kole orogba, ewe aje, igbin kan ao gun gbogbo repo man ose ao man fiwe.
AJE
Ewe aje ewe ogo iyere ao lopo ao fi se eyele kan lepo ni yo ti obe nan bati ji nan tan ao sadura si ao koje

Videos

Watch Otura Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Otura Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Otua Ofun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Otura Ofun Odu.