Ò
This Odu signifies the importance of awakening our Orí for personal and communal benefit.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Aja tuka agbarin
Adifafun ogbe ti o fi igo oti kan soso segun
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Kepe
Kejinana
Ewa bani laruse ogun
Ope arusegun laba ni lese oba orisa.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ifa ni ota wa fun elelyi ko rubo kole ba se gun won ko fi oti ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Asanko bialada
Apajuba bieledun
Eesun nikan ronini
Adifafun orunmila
Ti won ran ajogun merin wo silere
Ebo won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, iku paramo awo lo lode
Arun paramo awo lolode
Ewifun alejo kolo e fi sasara bagbo.
Ekan nan owo mi nijata
Erigimi nijobi erigi jobi
Kotomuti aida inu fifo ni tofo inu fifo ni todin Adifafun ajisebo
Ti i se omo bibinu agbonniregun
Ebo won ni ko se
O si gbebo nibe io rubo
Nje iku to ni oun opa ajisebo kole pa ajisebo mo
Haa ni mo se iku be lo pe yinda
Arun ofo
Gbogbo ajogun tiwon ni awon o se ajisebo won o les aji sebo mo
Haa ni mose ajogun bele peyinda.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki orubo ki ire o leba to lowo ifa ni korubo ni tori ajogun ifa ni ajogun merin nbo won o ma ba yaila re ki o fi owo kun ebo
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki orubo ifa ni awon ota po fun elelyi koruibo ko mabe eru ko
Sini oro akin lenu komo moja iya lawujo ki o se ma se etutu dada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan owo (igbale ) opolopo owo
Akuko adie opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ori omo sunhin baba omo
Adifafun jegbe
Tin re inu igbe lo he ire wale
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe o rubo
Nje irolo dolanmiran wa
Eyin o wojegbe kuro kuro
Iro lodola niranwa.
Akuko toko lana ikore loko
Adifafun erin tin sunkun pohun oni ola
Akuko toko lana iko re loko
Adifafun efon
Ti n sunkun pohun koniyi
Akuko toko lana ikore loko
Adifafun asin tin roko
Lo leela ebo won ni won o se
Won sigbebo nibe won rubo
Nje erin lola efon niyi esin nikan lo loko lola.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire fun eni toda ifayi korubo kole ba la ifani awon eyan manso pe irore po ifa ni irore yo di ola korubo
Ifa sope awon omo iya meta kan wa nibe yen ki won o rubo fun awon meteta ki won o le bani laari
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele akuko opolopo owo
Eku eja eyele akuko adire opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ididi kudi iwo lawo ile onidudu
Adifafun onidiku omo amejimojo awure
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje ididikudi io lawo ile onidiku
Ifa moje ki oju omo irunmole o ribi
Ajinigboro
Aringboro
Oburinburin bomi igboro boju
Oburin burin bomi igboro sinse
Emon igbo ni sare gonto gonto
Adifafun orunmila
Baba nlo le bawon fowo irukere mu le nigboro Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje aje tin o ni n ko nigboro lowa oore mi gbogbo Nigboro ire gbogobo temi ni n ko
Ni gbooro lowa oore mi gbogbonigboni.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ikayi ko rubo ki ojure komo bari ibi ki ojure kole mari ire kid elleyi ofi efun ati osun kun ebo
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ko rubo ifa ni oun pe ire ola fun ifa ni igbo ni oore re wa komo jina sibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo efun
Opolopo osun
Opolopo owo
Eyele
Akuko adire
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ori obo kan aso egungun lekeleke kan eyelefun fun kan ao lo ja ewe etiponola ao sookun mo ao wo wale ao wa jo pomo odidi atare kan aro sinu sere ao mo fi oti larolaro.
Ewe ola igba ati eyokan eso olowerenjeje igba ati eyokan odidi atare aojopo ao mo filo omigbonan tabi oti larolaro.
MEDICINE
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe ejirin tobile dada ao ja tiyopo ao wajo pomo abo adire kan pelu odidi atare klan ao ma fi feko tutu mu larolaro.
MEDICINE
Omo irula mokanla omo atara mokanla ao lo po mo arawon ao fi singbere iwori aweda si apa osi.
MEDICINE
Explore Ifa
Òtúrá Ogbè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Òtúrá Òyèkù, Òtúrá Iwòrì, Òtúrá Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òtúrá Ogbè Odu.
