Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Obara Oyeku

Obara Oyeku also known as Obara Yeku
Aliases: Obara Yeku
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for balance and harmony to achieve success.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/obara-oyeku
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Obara Yeku

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE IKINI Atare lose nu jinkun Ora kan nikun atare Adifafun esu legbe tise egbon monrari Igbati won nroko allero odun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe ki elelyi omon se ase ju lodo eni ti notju re pelu gbogbo nkan ti won nse fun ifa pe ti oba ti ni aseju yio pada si eni ete ni

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eja ajabo meji Ki won oti bori won Okete fi awon agbalagba Epo ati eko Akuko adie meji lebo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Obara oyeku Yeku yeku yekete Adifafun odan Odan nsawo losi ojuode
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Apa aja Itan esin Okere si nkanti agbalagba Mon pede lelori Adifafun olobara ti nsawo Lo sile oyeku egbon re

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe lara omo iya eleyi ni oore re wa ko mon se afojudi soro ebi rara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye Meji Eyele meji lako ati labo Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Obara oyeku Eeru ko eru louin osin oba Iworiko oloun osinm ogba mon Obinrin ko oloun ogba oorun oka Oun mon Adifafun bereri tise Aya agboniregun Ebo niwon ni kose O si gbebo n ibe o rubo Nje obara oyeku ta logbobeeri

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe saworo pepe topo dada, ao lo a o fise igbin meji, lepo niyo aote iyere osun ni obara oyeku afise ifa naje, aose adure si aokoje

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ewe eye aje obale mesan fun okunrin meje fun obinrin 7 eyo atare 9 mesan fun okunrin, eyo atare 7 meje fun obinrin, ori e eku emon ti won fi rubo won olopapo ao fi sin gbere si aarin ori lati iwaju de ipako MEDICINE

Videos

Watch Obara Oyeku teachings on our channel.

Explore Ifa

Obara Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Obara Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Iwori, Obara Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Obara Oyeku Odu.