Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtúrá Òsé

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the power of transformation and adaptability.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/otura-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni awamiwaja awo oloyo Adifafun oloyo To fi orile Ti nbo ado Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe orubo Nje amiwaja iwo ni awo oloyo Ori nigbeni ado ki gbeeyan Ori ni gbeni alaelu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa peki eleyi o mon gbokan le oogun ki o mon se etutu dada ki o si mon bori re dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

kofi eye etu bori kofi akuko adie meji kofi agbebo adie meji eku ati eja epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ebi npani koni gbere sinsin ninu Akasu banba ni won fi se oogun re Adifafun teyin gbiwa Tin lo ree sanwo onipin lorun Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe orubo Teyin gbiwa a Sanwo alaroka o Asinmin teyin gbiwa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe ki elelyi orubo isinmin lori gbogbo nkan tin se wahala le lori if ape etutu ni o gba kale

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Okete kan fun Akuko adie meta Eye etu meji Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ajikanse lekun Adifafun gbogbo okanra irunmonle Won ngbe EBO lo ode orun Ajikanse lekun Adifafun akilolo Akilolo ngbe ebo lo ode orun Ebo ni won ni ki won o se Akilolo nikan nibe leyin ti ntubo akilolo ni EBO wa o tete fin Ebo wa o tete da Ebo wa o tete dele eldumare juti gbogbo won lo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa peki eleyi o mon gi EBO se alo rara ki o tete mon rubo ti won ba ti sofun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele funfun Pepeye meji Akuko adie meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Piiti ni ese subu Alagemo ni oto sele Oto gele beni koto we sori Adifafun awurela Ti n sawo losi ode ijebu Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Nje opejin laape oniru Apejin leape oniyo Apejin apela lape ose awurela bijebu Ose awurela awo rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ki eleyi orubo si ibi ti elelyi nlo ki o le ba di eni ti won o mon sare ra oja re ki oja re mon ba kuta rara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eyele meji eyeetu meji agbebo adie meji okete kan Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE Ao toju ewe odundun ao te iyereosun ni odu ifa (ose tua) Ao da iyere osun si ara ewe odundun yi ao soro soke nibi ti ategun oti mon fesi

Videos

Watch Òtúrá Òsé teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtúrá Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Òtúrá Ogbè, Òtúrá Òyèkù, Òtúrá Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtúrá Òsé Odu.