Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifafun keke
Tii se omo iye olomijo
Iwori wotu peerepe
Adifafun okoto tise
Omo iye olomijo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Peerepe
Adifafun okoto
Okoto nlo eti okun lojo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Eyi minijo bi ikokun
Adifafun orunmila
Baba nbe laarin ota
Sangiliti ebo ni won
Ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Kee pe
Kee jina
Ewa ba wa laruse ogun
Iwori were
Babalawo ata
Adifafun ata
Igbati nfomi oju sogbere omo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori omo ki osi rubo ki araye o mon pa omo reje
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Okete kan
Epo
Eko
Agbeboadie meji
Okete
Akuko adie meji
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Adifafun elegiri
Igbati nsaye loun nikan
soso girogiro
Awo aboju kotokoto koto
Babalawo AJE
Adifafun AJE
AJE ntorun bo wa saye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki obo aje ki aje ole duro ti
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo igbin
Epo
Eko
Eyele funfun
Eye etu meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Awo etu, egbotude odidi atare kan, ao go papo ao mon te ni odu ifa iwori wotupere
ISEGUN
Epo ata ijosi aoloti o kunna
Dada ao po po mon ose dudu
Ao ko sinu poko agbon
Ao mon fi fo owo wa larolaro
Ao mon so nkan ti abafe si
Explore Ifa
Iwori Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Wotua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Otura Odu.
