Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Iwòrì Ògundà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Iwori Aweda
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for courage and determination.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/iwori-ogunda
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Aweda

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Eda o gbo ogun Ebo ni ifa ni ka mon se Adifafun ori Nijo ti fi omi oju Sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni ko mon se Osi gbebo nibe orubo Nje ire gbogbo Esa re wa ba ori duro Ori o ni ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon bo ori re dada ki o mon gbekele oogun nkan ki o si mon peese fun awon agbalagba dada kosi mon rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Akuko adie meji Eyele meji Okete Ki ofi eye etu kan Bo ori re pelu obi ati oti
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori aweda Eda ogboogun Ebo ni ifa ni ka mon se Adifafun orunmila Baba nfomi oju sogbere aya Ebo ni won ni ko mon se O si gbe bo nibe orubo Nje ekowo wa ewa yan Edu loko Akuko gagara koni kowo Se oko gbebo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire lati ipase obinrin fun eleyi, Ifa eleyii si nwa obinrin korubo daada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji Eye etu meji akuko kan Obi Oti Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori wo oun Rere da Iwori wo oun rere da Ifa bi o bada rere tan Ki o se rere ku fun mi Adifafun orunmila Baba nfomi oju sogbere aje Ebo ni won ni ko mon se Osi gbebo nibe orubo Nje iwori worere da fun miwa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii rubo ire gbogbo ki ire ole to lowo ki osi rubo nipase omo iyare kan ti yio laa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Akuko adie meji Eyeetu meji Epo ati eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ori okete meta ewe mon fowo ba omo mi pupo odidi atare meta ao jo papo Ao pe ifa si ao mon fi fo eko tutu mun lalelale

Videos

Watch Iwòrì Ògundà teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwòrì Ògundà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Iwori Aweda. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwòrì Ògundà Odu.