Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Iwòrì Óbárà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for careful planning and strategy.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/iwori-obara
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Adaba kenkeluku Babalawo aje Adifafun Aje Aje sawo lo si oja ojugboro mekun Ebo ni won ni kose Osi gbebo nibe orubo Nje adaba kenkeluku Kosile ta o mon aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ibi ti eleyi, ba nlo korubo ki ole ba gbayi nbe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pelu eyele Ogede omini Obi Oti Eyele meji Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ijo moti daye Nbere roko ri Adifafun adaba susu Nlo oko alero odun Ebo ni won ni ko se Osi gbebo nibe orubo Kee pe Kee jina Eba ni nijebutu ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii orubo nitori irin ajo to nlo ki osi rubo ntori omo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewure Obi Oti Igbin Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ni jo ti mo ti daye Nbere roko ri Adifafun alaimon isin Ope toji Ti n fi ojo edu yunko EBO ni won ni ko mon se Nje iwori ni o mon isin ope Loji nifi ojo edu yunko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii ojoko ti ifa ni ona abayore ki o mon dako ni asiko yi ti fa ni ko gbeju mon

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji Eyele meji Akuko adiere meji Epo ati eko Kosi mon bofa pelu Abo adie kan pelu obi ati oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Iwori obabira Babalawo ori Adifafun ori Ori nda se ayere lohun nikan soso Ebo ni won ni ko mose Ori si gbebo nibe orubo Nje kerekere Ori ni o sai di eleni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii orubo ki o mon ba da se aye re ki o le di eni apesin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Eyele funfun meji Akuko kan Epo ati obi Kofi eye etu kan bo ori re Pelu obi ati oti

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ori eye etu ti won fi bo ori re won o jo pelu oko atare kan ninu atare kan won o fi sin gbere si aarin orire

Videos

Watch Iwòrì Óbárà teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwòrì Óbárà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwòrì Óbárà Odu.