I
This Odu signifies the importance of patience and persistence.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Atepa Awori
Babalawo Erin
Lodifa ferin tin lo lee goke alo
Ebo won ni Ose
O gbebo nibe o rubo
Nje itaku to ni kerin man wo do
Toun erin lon lo
IFA IRETEDI ISEGUN
Kiwo Tedi Kemin Tedi
Eni esin ba te man re lonje aji besin
Adifa fun orunmila
Awon ajogun orun o je o sun man ju
Ebo won ni ose
O gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
Eba ni laru segun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo awon ota nda eleyi pada seyin, ibikan ree ti eleyi fee lo sugbon awon ota n di lowo won oje ki oroke tabi oore baba eleyi kan re awon ota ofe ki oto lowo Korubo
kire eleyi o leto lowo
Keleyi orubo amon ota koje ki eleyi osun, ki eleyii o rubo yio segun won, eleyii n la awon aala kan ti ko dara awon iko orun ni n won fe mu eleyi lo korubo kiwon o ma baa pa eleyii
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Ada kan
Agbado
Owo
Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Atepa Iwori
Babalawo oba
Lodifa fun oba
Ti n be laarin ota
Ebo won ni ko ba ose
Oba si gbebo nibe orubo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bawo laru segun
Kiwo Tedi Kemin
Eni esin ba fe ma repa lon je aji be
Adifa fun oosa nla oseremangbo
Ti n be laarin ota
Ebo won ni ose
O gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
E ba ni laru segun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Awon ota nda eleyi laa mun won ojeki pa re oka oun tin da wole ti eleyi bati pa se bee ni awon ota nyi mun si eleyi won oje ki ose oun tolese sugbon korubo a pare oman ka oun toba dawole
Keleyi orubo yio segun ota, keleyi o si fi ewure kan rubo eegun eyin eran yi ai fi kun ebo ru eje ara eleyi ao fi kun eboru nitori awon iko ti eleyin ri kadara korubo kole baa segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Oruka
Agbado
Owo
Epo
Eko
Agbado
Alabahun kan
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Atepa Awori
Babalawo oba
Lodifa foba oba
Igba ti n fomi oju sogbere aje
Ebo won ni oba ose
O gbebo nibe o rubo
Kee pe
kee jinan
Aje wa jede tuturu
Te nun man
Tie teni laa te nu man
Adifa fun dunundun
Ti o tenun rete di
Ebo won ni ose
O gbebo nibe o rubo
Oloun irete din
Undi irete di
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ni tori oju ajenpon eleyii, pe ajenbo feleyi ki osi rubo senu ise re, yio la gidigidi kosi maa so ooto
Keleyi orubo ire ajenbo fun eleyi ti gbogbo aye osi man wipe ajede feleyi ki eleyi obun awon oni lu lowo ko si man lo si bi ti won ba tin se ariya daa da ni be ni re aje re yio ti to lowo ko si man wo aso daa da
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
Epo
Eko
Agbado
Eyele meji
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Epo lose je su
Akaso lodun gaka
Obinrin se barin jokunrin lo
Adifa fun oosala osere mangbo
Tin sun kun poun otoju bare
Ebo won ni ose
O gbebo nibe o rubo
Nje morire nile
Morire loko
Ire to so nun ire de
Kete Kete Abeeku poo poo
Adifa fun orisa oko
Nijo ti n sawo rebi atoke doke
Ebo won ni ose
O gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
Aje wa je de tuturu.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyiorubo gbogbo oore eleyin lo ko yale re korubo kire olee yalere papa julo omore kan re ki won o maa borisa fun un, ori omo yii yoo man lanan fun baba re oore meji kan sin bo fun eleyi korubo leba do lomo
Keleyi orubo daa da kaleyi ba se ru bo si bee ni re aje re yio se po to, ibikan si lele yin lo yi pe yio rire munbo keleyi osi man soro to dara lenu ni pa se bee ni re eleyi yio se telowo Ko si man bo aje daa da
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi igbin meji borisa pelu obi meji
Epo
Eko
Agbado
Abodie kan
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Isu ogiri sako eepo obo eeru alamo ao gun po man ose ao ti opolo aaye kan tele igba olomori ao ko ose lori ao man bu we
ISEGUN
Ao to ju ikoko kana so eleyi wo to fi dafa ao ko tele ikoko yi ao ko ewe peregun merindinlogun le lori eleyi yio fa omin fo orire si nu ikoko yi ao de pada ao lo bo man inun igbo
Explore Ifa
Iwòrì Ìrètè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwòrì Ogbè, Iwòrì Òyèkù, Iwòrì Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwòrì Ìrètè Odu.
