I
This Odu represents the need for careful planning and strategy.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ijo moti daye
Nbere roko ri
Adifafun adaba susu
Nlo oko alero odun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo nitori irin ajo to nlo ki osi rubo ntori omo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure
Obi
Oti
Igbin
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ni jo ti mo ti daye
Nbere roko ri
Adifafun alaimon isin
Ope toji
Ti n fi ojo edu yunko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii ojoko ti ifa ni ona abayore ki o mon dako ni asiko yi ti fa ni ko gbeju mon
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie meji
Eyele meji
Akuko adiere meji
Epo ati eko
Kosi mon bofa pelu
Abo adie kan pelu obi ati oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori obabira
Babalawo ori
Adifafun ori
Ori nda se ayere lohun nikan soso
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo ki o mon ba da se aye re ki o le di eni apesin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Eyele funfun meji
Akuko kan
Epo ati obi
Kofi eye etu kan bo ori re
Pelu obi ati oti
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori eye etu ti won fi bo ori re won o jo pelu oko atare kan ninu atare kan won o fi sin gbere si aarin orire
Explore Ifa
Iwori Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Obara Odu.
