O
This Odu signifies the journey of perseverance and strength.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Eesin were ni fi ide were soju
Adifafun orunmila
Ifa n sawo relu ekun
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Asa korongbo opeda
Adifafun okanbi
Tii se omo bibinu agbonniregun
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Eyi n mo kora egbeje
Ara kan yin ni egbefa kan na nkan nan mija sonu un o ri mo
Adifafun gbogbo okanle ni irunmole
Nijo won nlo salade orun
Adifafun orunmila
Nijo ti baba n lo sode orun
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ide ni ojo birin
Irin ni o jo bi ide agbalako
Agaolako ki inu alako o baje
Adifafun folubisi
Ti won ni won o nigbo isire mo laye
Explore Ifa
Otura Okaran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Otura Okaran Odu.
