O
This Odu emphasizes the importance of embracing change and new beginnings.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Oturupon yekuyekute
Adifafun ori nijo tisuku pe oun
Koleni kan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki elelyi olobo orire tori ire
Gbogbo kio lo fi eja aro bo ori
Re kio si fie ran oruko kan
Rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Eja aro funfun kan
Epo
Eko
obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ayeku yeku gbijo
Orisa akogbode
Adifafun orisa nla osere mongbo
Nijo ti n momi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire omo fun elelyi ki eleyi olobo orisala tori omo kio lofi eye etu ati igbin mejo bo orisala kiop si rubo fesu pelu gedegede owo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Igbin mejo
Epo
Eko
Obi
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ipe tape sinku
Abape sin olokuru aye
Adifafun egun abu forisa
Adifafun aje nijo ti
Awon meteta n tode orun bo waye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pere aje fun elelyi pe
oju aje nip on elleyi kio lo fi agbo
bo aje kio si fi akuko rubo fe sun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran agbo kan
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ayekuyekun gbijo
Orisa ako gbode
Olufon orolu gbijo
Orisa ako gbode
Adifafun ejidun oun ile jo hun
Sota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire isegun fun eleyi ki elelyi olobo ile ni opolopo ekuru ati igbin kio si fi akuko adire meji rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Ekuru
Igbin merin
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe awayoyo pelu ewe
saworopepe ao wa gun mon
ose dundun ao wa fi oti oyibo po
ao wa kosi un isasun olomonrin
kana o wa mon buwe laro laro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju yerupe atalade ao toju
obi ori orisala ao wa lo mejeji
papo ao wa fi si gbere lari ja
ao wa fi epo pupa la iyokun
lale taba fesu
Explore Ifa
Oturupon Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Iwori, Oturupon Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Oyeku Odu.
