Ese — Yoruba Verse
Oturugbowu lebelebe
Komu le oju oruloran
Adifafun araba pataki
Ti n be laarin ota
Ebo ni won ni ko se
Osi gbebo ni be orubo
Nje bi araa bara won ori
Igin oko ni mon rale lori
ESE IFA
Ori ko ku awo won lode egba
Sunbola awo won lode Ijesa
Abu sun daja ni sawo won ni kotewerenjeje
Adifafun omowunmi
Omo ataso gbomo lowo won
Igba ti n momi oju sogbere omo
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Kee pe
Kee jinan
E wa bani ni jebutu omo.
ESE IFA
Ore ayanyanju
Ni mun won yan ore ekore
Ayanyanju
Ni mun won yan oore o dale
Adifafun akuko ti se ore kolokolo
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Ero ipo
Ero ofa
Eyin o fi rina fa kan nin ti jo won.
ESE IFA
Otua ganga
Iwori naa ganga
Okunrin ganga ko mo dido bale fun okunrin ganga mo
Adifafun orunmila
Baba n sawo rode isan
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje ijowon buo ni san
Ifa emi o si nibe.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni pe oun pe ire isegun fun elleyi ki elelyi ofi odiid eran oruko kan kun EBO run ati opolopo otutu
Ifa pere fun eni toda ifayi, ifa ni gankan yi toju omo n pon ifani aso kan nbe ninu ile eleyi ito filo ifani ko fi rubo nitori omo tabi oun ati awon kan jo fera aso kana won yo kuno ri owo oun nikan lo lodara ifani ko firubo tori ko leba bimo.
Ifa pere fun eni to da ifa yii ifa ni ki eleyi o rubo if ape koma fi inu han ore ko ma ba pa ifa ni oore kan ni yi ti won jo feran ara won tiwon jo wa arawon ifa ni ore yi ma n beru re pelu in kan to n fi se agbara if ape ore yo wa b ape ko se idi agbara naa fun oun komo so o fee pa ni.
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ara koro eleyi ko rubo ifa ni eleyi o se ore fun enikan yow a fibu su ifa ni ko mo ba eni naa if ape oun loun ogbija eleyi kobere oun ti fa o gba ko si bo ifa dada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Opolopo otutu owu
Owo pupo
Epo
Eko
Obi
Agbebo adie
Opolopo owo
Oruko
Opolopo owo
Agbebo adie
Eku
Eja
Eyele
Akuko adie
Opolopo owo.