Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Oturupon Owonrin

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in life's journey.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/oturupon-owonrin
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Opolopo lagbebata kaya monlu
Adifafun onipo alaelu
Omo aro gegejoba
Won ni korubo nilaku arare
O sigbebo nibe orubo
Ero po
Ero ofa
Ewaba ni laiku ganginrin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire aiku fun eleyi
EBO ni kio se ki eni re legun
kio si fie ran oruko kan rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan
epo
eko
obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oturupon won nifa
Omo awo koriki nibe
Lenu awon agba sakosako
Logbedun
Adifafun orunmila
Nijo ti baba n torun bowaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe iwe laiku fun elelyi
EBO aiku ni kose kio si lobo ogun
pelu oja kan kiop si rubo fesu
pelu akuko adire meji

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi aja kan
Akuko adire meji
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

oturupon won nifa
omo awo kori ko nibe
lenu awon agba sakosako
logbedun
adifafun irawa saswa ti somou kunrin igbalajo igbati momi oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pere gbogbo fun elelyi ebo ni ki elleyi ose kio si lobo orisa agbarawo pelu eye etu meji ati igbin mejo ki okiki re oleba kan kaye kio si fi akuko rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eye etu mei
akuko adire kan
igbin merin
epo
eko
obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Opolo logbe bata kaya mon lu
Adifafun onipo alaelu
Omo aji fagungun eran rubo
Igba ti n momi oju sogbere ire
gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa sope ki elelyi orubo ola pe oju
aje nipon eleyi ki elelyi osi lofi
agbo bo ifa ki ire ola bato lowo lodun yin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agbo odundun kan
Epo
Eko
Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao ewe okika ti se ewe iyeye ao
ju ewe wla ewe saworo pepe erele
ewe iroko ao wa jo gbogbo re papo
ao war o sinu sere kana o wa
pa akuko adire kan fun ao wa
mon fi fo eko tuntun mu laro laro

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe egungun orun ao to ju ewe keyin soru ao wa lopo mon iyere ao wa fi se igbin apinnu kan lepo niyo ao wa so gbogbo oun aba fe si ao wa je obe naa agbodo mon je oba naa ni emeta lodun kan.

Videos

Watch Oturupon Owonrin teachings on our channel.

Explore Ifa

Oturupon Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oturupon Owonrin Odu.