Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Ògundà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the need for thoughtful decision-making and strategic planning.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-ogunda
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oturupon gunda Oturu gede Adifafun elegede Ti nlo oko aileron lodun Ebo ni won ni kose Osi gbebo nibe orubo Nje eropo Ero ofa Ewa bani nijebutu ire gbogbo Ao toju ewe ogbo ewe oki ka ao wagon mo ose dundun ao w ate iyere osun ni odu ifa yi ao wa se adura si ao wa po mon ose yin ao wa mon fi we laro laro

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire fun eleyi ni okere pe ibikan ni elelyi loyin ebo ni kose kio si lobo ori re pelu eja aro kio sifi akuko meji rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Eja aro kan Epo Eko Obi Oti
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oturupon gunda Oturupon gede Gedegede ni won tapa elelgede Adifafun orisala osere mongbo Nijo ti nlo oko ailero lodun Ebo ni won ni kose Osgbebo ni be orubo Nje kini orisarola Oko lorisa rola Oko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire okere fun elelyi ki elleyi olobo orisa la pe lu opolopo igbin mejo kio si fi owo rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igbin mejo Opolopo owo Eko Epo Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Gbinrin aro Kike aja gboungboun Adifafun orunmila Baba ji baba korowo kan Ayonaa Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be o rubo Ifa o to gege ki n ri aje temi ka Gbinrin aro kiki aja gboungboun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire ola fun elleyi ki elelyi olo bo ifa pelu ewure kan kio si fi obi bo orire

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Opolopo owo EBO Obi Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oturupon gunda Oturupon gede Gedegede ni won tape elegede Adifafun gbeku nijo titi roko ode Ti kori kankan pa Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje gbeku perin kini ewi win Gbekenperin kiini ewin Kinla Moyogidigidi moyofun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire oloa fun elelyi ,ki elelyi olobo ogun pelu aja ewe emin esusus obi kio si fi eran oruko kan bo ifa pelu owo pupo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Eran aja kan Ewa Emun Isu Obi Owo Epo pupa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju awo ilu ogindingbo ao wa toju ewa apada ao wa toju odidi atare kana o wa jo gbogbo re po ao wa fi si gbere lari ja ao fi epo pupa la iyoku lale sun

Videos

Watch Òtùrùpòn Ògundà teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Ògundà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Ògundà Odu.