Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Oturupon Obara

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu represents the balance between wisdom and action in decision-making.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/oturupon-obara
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Pondara pondara
Adifafun ayinsatu abomon bere
Igba ti n momi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire omo fun elelyi ki eleyi orubo omo pe oju omo ni po kio lofi eku meji eja meji abodie meji bo ifa kio le babi mon.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji
Eja meji
Abodie meji
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oturupon gbara
Babalawo ori lose fafun ori
Ori suku pe oun olehi kan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire gbogbo fun
eleyi ebo ni ki elelyi ose ki ire gbogbo ole ba to lowo kio si lobo ori re pelu eye etu kio si fi oruko rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan
Eye etu kan
Epo
Eko
Obi
Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Badafa babalawo yio jehun
Badafa babalawo yio jehun
Abente mon tie darara
Baba lawo yio jehun
Adifafun ifa fimi somo tise
Omo bibi inu agbanmeregun
Igbati momi oju sogbere
Ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi ki elleyi orubo ki iregbogbo Ole bato lowo kio lo bo ifa pelu ewure ati eku emon lopolopo kio si fi akuko adire rubo fesu odara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan
Eran ewure kan
Opoloopo eku emon
Epo
Eko
obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Akogin lapa
Ofin arare sokudigi
Adifafun oturutise omo iya abera
Igba ti won sawo rebi atoke doke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pre ire gbogbo fun omo
iya meji EBO ni ki won ose
ki won osi lobe ori won pelu agbon kiwon o gbebo nibe o rubo fesu pelu pepeye meji

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

pepeye meji
agbon meji
epo
eko
obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe amon ati iyere ao wa toju eku emon meta ao wa se mon ewe ti alo yin ao wa mu iyere osu ao w ate ni odu ifa oturupon dara ao wa se adura si ao wa je obe yii

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ewe agogo igun ao toju ise eta ati ewe segun sete ao wa gun gbogbo re mon ose dudu ao wa mon fi ose naa we larolaro

Videos

Watch Oturupon Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Oturupon Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oturupon Obara Odu.