Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Iwòrì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Panlawi ponlawin Adifafun orunmila Nijo ti baba n lole yo oku ninu olaye Ebo ni won kose O si gbebo nibe orubo Nje, eniyan to fi omon pon kowa sakin Oturupon din Oturu pepe Adifafun orunmila nijo ti Babalole ba olu tayo lafin Ebo ni won ni kose Osigbebo nibe orubo Nje mobolu tayo Morire Emibolu tayo Obalami Mobolu tayo Morire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe oun pe ire omo fun elelyi EBO ni kose kio silo bo ifa pelu eran ewure odidi kan Ifa sope oun pe ire gbogbo fun eleyi pe ibikan ni eleyi loyi korubo kole bagbayi bo ni be kio lobo ifa pelu eran ewure

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure odidi kan Epo Eko Obi Eran ewure kan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ogede dundun awo iwere Adifafun erinlegbejo ilawo Nijo ti won kowo rode oyo Ebo ni won ni ki won ose Won sigbebo nibe wonrubo Nje, okudede kiwon odeja Ni oba ejio bateri gbaso Oturupon din eyeba Oturupon din eyefo Baba lawo aje lofefa fun aje Nijo ti aje torubo waye Ebo ni won ni kose Osigbebo nibe orubo Nje aje loni se Fiso sile awo Aje loni so

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire isegun pe oun pe ire aiku fun eleyi ki eleyi osi mon daja kio bo orisala pelu igbin merin kio fi akuko adire bo esu ifa ni oun pe ire aje fun elelyi pe oju aje lopon elleyi kio lobo aje pelu eye etu ekuru ogede eyin oyin obi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Igbin merin Epo Eko Obi Eye etu Oyin Eyin Ekuru Obi oti Epe Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Lata npopo awo egbe Adifafun won ni monlasese agere Nijo ti won momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni ki won ose Won gbebo ni be orubo Nje leyin ni ewure yo yo Leyin ni ewo re yoyo baba mon igi losan akiwa gbongbo re lorun adifafun lemorun ti se obinrin imonle won ni korubo nilaku arare osigbo ni be orubo eropo ero ofa ewa bani laiku kanginrin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun eleyi ki eleyi olobo aje pelu eye etu kio sifi eku eja agbebo adire kan bo ifa ifa sope oun pe ire aiku fun eleyi ki elelyi olobo orisala pelu opoloo igbin kio sifi eran oruko kan tu ebo fun esu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Abo adire kan Eja Obi Epo Eko eran oruko kan opolopo igbin epo eko obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ponlawi Ponlawin Adifafun Ipon ni jo tigbogun lo ilobe Ebo ni won ni kose Ogbebo ni be orubo Ero ipo Ero ofa Ewa bani laru segun Oturupon din eyeba Oturupon din eyefo Eyinla loko gbinringbinrin Lianu ni bawon jo ilu duruku Adifafun won ni ilu monsuru Adifafun won ni illu monsere Nijo ti won ni kiwon orubo Ni tori ajogun EBO ni won ni kiwon ose Won si gbebo nibe won rubo Nje eyin epele aralu monsuru Epele ara ilu mon sere Gbebo imonle lokuku metala Alanu wa kibaru

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire isegun fun elelyi ebo ni ki elelyi ose kio si fin oruko kan ru ebo ifa ni oun ope ire isegun fun elelyi ki elelyi olo fi ewure meji rubo kiwon ofi okan bo ifa ki won ofi okan pe se fun awon agbalagba EBO Eran ewure meji Epo pupa pupo Eko Obi Oti

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko odidi kan epo eko obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ele wa ao wa gun po mon ose dundun ao wad a lofinda si toba lorudaradara ao wa ko sinu ike funfun ao wa mon fi we larolaro AWURE ao toju ewe gbodogin pelu iyere ao wa lopo ao wa fi se igbin mefa lepo ni yo ao wa ja igbin yi ni idi ao ko idire dede yi sibika pelu gbogbo awon oun ti abale se nui be sinu agbada ao wa tunmu ewe gbodogin yi si ao wa jo po mon odidi atare kana o wa je obe yi ao mon fi oti lo ebure

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ISEGUN Ao toju igi legunoko ao toju ogede dundun pelu atare kana o wa jo papo toba jo tan ao wa fi si gbere ogoji ati eyo kan si arin ori wa fi iyoku fo eko mu iya yin ao toju ewe apada ati ewe segun sete ao wa gun mon ose dundun ao wa mon fi we laarolaro

Videos

Watch Òtùrùpòn Iwòrì teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Iwòrì Odu.