Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Òwónrìn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in life's journey.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-owonrin
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Opolopo lagbebata kaya monlu Adifafun onipo alaelu Omo aro gegejoba Won ni korubo nilaku arare O sigbebo nibe orubo Ero po Ero ofa Ewaba ni laiku ganginrin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire aiku fun eleyi EBO ni kio se ki eni re legun kio si fie ran oruko kan rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan epo eko obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oturupon won nifa Omo awo koriki nibe Lenu awon agba sakosako Logbedun Adifafun orunmila Nijo ti baba n torun bowaye Ebo ni won ni kose Osigbe bo nibe orubo Nje emi obawon wa Ti emi obanwon lo Ni kanhinkanhin ni motode

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe iwe laiku fun elelyi EBO aiku ni kose kio si lobo ogun pelu oja kan kiop si rubo fesu pelu akuko adire meji

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi aja kan Akuko adire meji Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

oturupon won nifa omo awo kori ko nibe lenu awon agba sakosako logbedun adifafun irawa saswa ti somou kunrin igbalajo igbati momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni kose O si gbebo ni be orubo Nje, bi alele batile o Osupa abegbeje irawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pere gbogbo fun elelyi ebo ni ki elleyi ose kio si lobo orisa agbarawo pelu eye etu meji ati igbin mejo ki okiki re oleba kan kaye kio si fi akuko rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eye etu mei akuko adire kan igbin merin epo eko obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Opolo logbe bata kaya mon lu Adifafun onipo alaelu Omo aji fagungun eran rubo Igba ti n momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Nje odun odun ni kogba egungun agba ginrinsa logba

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa sope ki elelyi orubo ola pe oju aje nipon eleyi ki elelyi osi lofi agbo bo ifa ki ire ola bato lowo lodun yin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agbo odundun kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao ewe okika ti se ewe iyeye ao ju ewe wla ewe saworo pepe erele ewe iroko ao wa jo gbogbo re papo ao war o sinu sere kana o wa pa akuko adire kan fun ao wa mon fi fo eko tuntun mu laro laro

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe egungun orun ao to ju ewe keyin soru ao wa lopo mon iyere ao wa fi se igbin apinnu kan lepo niyo ao wa so gbogbo oun aba fe si ao wa je obe naa agbodo mon je oba naa ni emeta lodun kan.

Videos

Watch Òtùrùpòn Òwónrìn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Òwónrìn Odu.