Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Òyèkù

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of embracing change and new beginnings.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-oyeku
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oturupon yekuyekute Adifafun ori nijo tisuku pe oun Koleni kan Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Nje, oju toni oun o ni ba orisa se Kere kere won yio pada wa to ori wa Kere kere Gbogbo ara tiwon ni awon Oni ba ori se Kerekere Won yio pada to ori wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki elelyi olobo orire tori ire Gbogbo kio lo fi eja aro bo ori Re kio si fie ran oruko kan Rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Eja aro funfun kan Epo Eko obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ayeku yeku gbijo Orisa akogbode Adifafun orisa nla osere mongbo Nijo ti n momi oju sogbere omo Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Nje, ayekuyekugbijo Orisa ako logbode Olufon orolu gbijo Orisa akologbode Nje, ta laa mon si borubepe Orisa lamon si borubape

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire omo fun elelyi ki eleyi olobo orisala tori omo kio lofi eye etu ati igbin mejo bo orisala kiop si rubo fesu pelu gedegede owo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Igbin mejo Epo Eko Obi Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ipe tape sinku Abape sin olokuru aye Adifafun egun abu forisa Adifafun aje nijo ti Awon meteta n tode orun bo waye Ebo niwon ni ki won ose Aje nikan ni nbe leyin ti n rubo Nje ategungun o Atoria totito Laje juwon lo Ko si runmonle bi aje mon

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pere aje fun elelyi pe oju aje nip on elleyi kio lo fi agbo bo aje kio si fi akuko rubo fe sun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agbo kan Akuko adire kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ayekuyekun gbijo Orisa ako gbode Olufon orolu gbijo Orisa ako gbode Adifafun ejidun oun ile jo hun Sota Ebo ni won ni ki ile ose Nje ejidun toni oun opale Arare lapa Ejidun tomi oun opale Olapale mon arare lopa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire isegun fun eleyi ki elelyi olobo ile ni opolopo ekuru ati igbin kio si fi akuko adire meji rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Ekuru Igbin merin Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe awayoyo pelu ewe saworopepe ao wa gun mon ose dundun ao wa fi oti oyibo po ao wa kosi un isasun olomonrin kana o wa mon buwe laro laro

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju yerupe atalade ao toju obi ori orisala ao wa lo mejeji papo ao wa fi si gbere lari ja ao wa fi epo pupa la iyokun lale taba fesu

Videos

Watch Òtùrùpòn Òyèkù teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Òyèkù is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Iwòrì, Òtùrùpòn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Òyèkù Odu.