O
This Odu signifies the journey of perseverance and strength in overcoming challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Otutu kinpokanran
Adifafun alare obosikun
Igba ti n momi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi ki elelyi olobo ifa pelu eran ewure kio si lobo orire naa pelu eyele kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eran ewure kan
eyele kan
epo
eko
obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Otatoto
Orooro
Ototo lajepa
Ototo laje mumu
Lotootot ni mon folu esinsin seun
Ejo ni fi ibi werewere wogbo
Adifafun oturu tise omo iya okanra
Igba ti won momi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire fun omo iya meji EBO ni ki mon ose ki won osi lofi odidi elelde bo ifa ki won ole beri se
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
odidi elede kan
epo
eko
obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Otutu kipokanran
Komo owo obosiku
Adifafun orisala osere mongbo
Ti lo oko aileron oduu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa perire okere fun elelyi ki elleyi
orubo kio si lobo orisa la pelu
opolopo igbin kio si fi akuko adire rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
akuko adire kan
opolopo igbin
epo
eko
obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
oturupakan
olokanran pakan
baba lawo apa lose fa fun apa
apa momi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire omo fun elelyi amon ki elelyi orubo kii awon omo naa ole bASE ni ahunfani ni ojo iwaju kio sib o ori re pelu opolopo ede pupakio si fi eku eja agbebo adire bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodie kan
Opolopo ede pupa
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju imin esi ao tioju ewe ogo pupo ao loju dewe saworo pepe pupo do toju ewe oriji pupo ao wa jo gbogbo re pao mo odidi atare kana o wad a si meji ao po okan monn ose dundun ao ro ekeji sinu ato kan ao man fi fo eko tuntun mu ao mon fi ose be we laro laro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ipepe irin alagbede ao to ju ori aginliunti kana o tojku ewe apada ao wa jo mefefa po ao wa dasinu ipara toba wuwa ao wa mon fi para mi gbogbo igba
Explore Ifa
Oturupon Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Okanran Odu.
