Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Òkánràn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the journey of perseverance and strength in overcoming challenges.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-okanran
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Otutu kinpokanran Adifafun alare obosikun Igba ti n momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni ko se Osigbebo ni be orubo Nje ifa monje kibosiku o Moti di ewe ayomonyoye Emi ogbedo bosi dagba

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi ki elelyi olobo ifa pelu eran ewure kio si lobo orire naa pelu eyele kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran ewure kan eyele kan epo eko obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Otatoto Orooro Ototo lajepa Ototo laje mumu Lotootot ni mon folu esinsin seun Ejo ni fi ibi werewere wogbo Adifafun oturu tise omo iya okanra Igba ti won momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni kiwon o kose Won si gebo nibe orubo Nje otutu kipokanran Komon awo obosiku o Esin lamon gun sawo wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire fun omo iya meji EBO ni ki mon ose ki won osi lofi odidi elelde bo ifa ki won ole beri se

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

odidi elede kan epo eko obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Otutu kipokanran Komo owo obosiku Adifafun orisala osere mongbo Ti lo oko aileron oduu Ebo ni won ni kose Osigbebo nibe orubo Nje kini orisa rola Oko lorisarola oke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa perire okere fun elelyi ki elleyi orubo kio si lobo orisa la pelu opolopo igbin kio si fi akuko adire rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

akuko adire kan opolopo igbin epo eko obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

oturupakan olokanran pakan baba lawo apa lose fa fun apa apa momi oju sogbere omo Ebo ni won ni kose osigbebo nibe orubio nje okere lomo apa lasi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire omo fun elelyi amon ki elelyi orubo kii awon omo naa ole bASE ni ahunfani ni ojo iwaju kio sib o ori re pelu opolopo ede pupakio si fi eku eja agbebo adire bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodie kan Opolopo ede pupa Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju imin esi ao tioju ewe ogo pupo ao loju dewe saworo pepe pupo do toju ewe oriji pupo ao wa jo gbogbo re pao mo odidi atare kana o wad a si meji ao po okan monn ose dundun ao ro ekeji sinu ato kan ao man fi fo eko tuntun mu ao mon fi ose be we laro laro

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ipepe irin alagbede ao to ju ori aginliunti kana o tojku ewe apada ao wa jo mefefa po ao wa dasinu ipara toba wuwa ao wa mon fi para mi gbogbo igba

Videos

Watch Òtùrùpòn Òkánràn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Òkánràn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Òkánràn Odu.