Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Òsé

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the power of transformation and the need for adaptability in the face of change.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oturupon se Awo eja losefafun eja Nijo ti momi oju sogbere omo EBO ni won ni kose Ogbebo ni be orubo Nje kosibi ta kan Odo taka omo eja ao toju ewe emini ewe sefun sefun ao wa fi se eyin adire meje lepo ni yo ao wa ta oyin die si ti obe naa baji naa ao se adura ao wa koje lese kese

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pere omo fa eleyii pe oju omo n pon elelyii ki o lo bo ifa leku leja labo die yio bimon

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodire kan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oturupon da seke Obadade owo Oturupon n daseke Oba tepa ileke Oturupon daseke Abada buro oje Adifafun iyalode ipo Eyi ti yio lewure daran daran nile Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje otukoran bow a o Ewure abenu funfun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire isegun fun eleyi ki eleyi olo fi ewure ti enu rwe ba funfun ifa kio si loru bo fesu pelu akuko adire

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Akuko adire kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oturupon dasedase Adifafun ase bagebage Ti moni opju sogbere omo Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje morase mi Mo sasemi Oloru jekodo mo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire omo fun eleyi ki eleyi orubo omo pe oju omo nip o yio lobo ifa pelu eye pepeye meji

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji Epo Eko Obi Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oturupon daseke Oba n dade owo Oturupon n daseke Oba n tepa ileke Aba daburo oje Adifafun egungun Abu fun ogun Abu fun orunmila Igbati won momi oju sogbere Aje Ebo ni won ni kiwon ose Orunmila ni be leyin tirubo Nje eropo Ero ofa Ewa bani ni jebutu ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi pe awon kan ni won omon ba fi ori gbari korubo ki ore wo oleba di tie ki ole fi ewure bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

inu enure ao wa lopo ao wa o mon ose dudu ao wa fi we fun ojo meje

Videos

Watch Òtùrùpòn Òsé teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Òsé Odu.